Welcome!
Login Register
Home View New Posts Help
Osogbo nro keke fun awon Oloselu PDP ni Ogo-Oluwa L'osogbo
Lati bi agogo mejila Owuro, Ojo Aje, ni gbogbo Ogo-oluwa ti n ro keke, bi e ni wipe,nise ni won tu awon Oloselu PDP sita, nise ni won korin lotun losi, ti gbohun gbohun won si n ja ketekete yi ka gbogbo adugbo naa. Eni to ba debe lo le so, iye awon oko ayo kele to lu ibe pa, Kama paro, owo nbe lowo awon Oloselu yi o. Faforiji lo ko awon eniyan sodi wa si ile-oselu won to wa logo oluwa, okan ninu awon oro oloselu ti gbohun gbohun ti jade lati ibe jade wipe "Bi awon kan se n je lotun losi to, kohan lara won,sugbon nigba ti a wa lori ijoba, eku n ke bi eku, eye si n ke bi eye, sugbon nibayi, Ojugbogbo wa naa tiri ohun to n sele, abi", Gbogbo awon olugbe adugbo naa le jersi irokeke awon Oloselu yi nibe loni. 

Abi iro ni mo pa ni?
Quote
emi o mo.... tori Mi KO sinibe
Quote
PDP lo se o.
Quote

Return to Top Official Website